![]() |
Orebro jade si agbaye je ajo toun moju to ohun elo nipa ayika ni ile Sweden ati Ohun amu se agbara kakakiri ori le ade agbaye.A ni ajosepo pelu orisirisi ile ise toun pese ona abayo nipa ohun a mu se agbara lati ara ategun, oorun and ooru.Awon, alamojuto wa je awon atohunrinwa to ka iwe, ti won si ngbe orile ede Sweden. Won je awon ti o dangajia ninu ede (ede orisirisi bi marundinlogun), ti won si ni asoju si awon orile ede bi, orile ede alawodudu, Aarin gbugbun ila oorun, aarin awon alawofunfun, orile ede China ati India, Aje asoju orebro ti ohun risi ajo ilu, asi tun ni ajosepo pelu ajo okowo ti Malardaun ati ajo isejoba to orebro.A le pese alaye nipa ohun elo ayika ti o peye ni ilana to ilu america ni orisirisi ede.A le se eto, ifojukoju pelu awon alase ibile ati awon ile-ise tohun se eto itoni sona, iranlowo ati anfani nipa eto okowo ni orile ede Sweden.Osese ki a ranse pe awon to o ba ni ife si eto yi lati gba alaye nipa awon ohun elo ati lati se pasi paro imo. |
|||||||||
![]() |
||||||||||
Fun alaye siwaju si, kan si wan ni: |
||||||||||
|
||||||||||
|
||||||||||
WWW.OREBROGOESGLOBAL.SE |
||||||||||